Psalm 19 in Yoruba Language

Discover the beauty and depth of Psalm 19 in Yoruba, unlocking the rich meanings of each biblical sentence. This step-by-step translation provides a contextual understanding that is engaging and easy to follow.

Psalm 19 in Yoruba

1. Ojú ọ̀run ń sọ̀rọ̀ ògo Ọlọrun, òfuurufú sì ń kéde iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀.

  • The heavens declare the glory of God; the skies proclaim the work of His hands.

2. Ọjọ́ dé ọjọ́ ń sọ ọ́ ní àsọgbà, òru dé òru sì ń fi ìmọ̀ rẹ̀ hàn.

  • Day after day they pour forth speech; night after night they reveal knowledge.

3. Wọn kò fọ èdè kankan, wọn kò sì sọ ọ̀rọ̀; bẹ́ẹ̀ ni a kò gbọ́ ohùn wọn;

  • There is no speech or language where their voice is not heard.

4. Sibẹ ìró wọn la gbogbo ayé já, ọ̀rọ̀ wọn sì dé òpin ayé. Ó pàgọ́ fún oòrùn lójú ọ̀run,

  • Their line has gone out through all the earth, and their words to the end of the world. In them, He has set a tabernacle for the sun.

5. Tí ó ń yọ jáde bí ọkọ iyawo tí ń jáde láti inú yàrá rẹ̀, ati bí akọni tí ara ń wá láti fi tayọ̀tayọ̀ sáré ìje.

  • Which is like a bridegroom coming out of his chamber, and rejoices like a strong man to run a race.

6. Láti apá kan ojú ọ̀run ni ó ti ń yọ wá, a máa yípo gbogbo ojú ọ̀run dé apá keji; kò sì sí ohun tí ó bọ́ lọ́wọ́ ooru rẹ̀.

  • His going forth is from the end of the heaven, and his circuit to the ends of it: and nothing is hidden from the heat thereof.

7. Òfin OLUWA pé, a máa sọ ọkàn jí; àṣẹ OLUWA dájú, ó ń sọ òpè di ọlọ́gbọ́n.

  • The law of the LORD is perfect, converting the soul: the testimony of the LORD is sure, making wise the simple.

8. Ìlànà OLUWA tọ́, ó ń mú ọkàn yọ̀, àṣẹ OLUWA péye, a máa lani lójú.

  • The statutes of the LORD are right, rejoicing the heart: the commandment of the LORD is pure, enlightening the eyes.

9. Ìbẹ̀rù OLUWA pé, ó wà títí lae, ìdájọ́ OLUWA tọ́, òdodo ni gbogbo wọn.

  • The fear of the LORD is clean, enduring forever: the judgments of the LORD are true and righteous altogether.

10. Wọ́n wuni ju wúrà lọ, àní ju ojúlówó wúrà lọ; wọ́n sì dùn ju oyin, àní, wọ́n dùn ju oyin tí ń kán láti inú afárá lọ.

  • They are more desirable than gold, even than much fine gold: sweeter also than honey and the honeycomb.

11. Pẹlupẹlu àwọn ni wọ́n ń ki èmi iranṣẹ rẹ, nílọ̀, èrè pupọ sì ń bẹ ninu pípa wọ́n mọ́.

  • Moreover by them is your servant warned: and in keeping of them there is great reward.

12. Ṣugbọn ta ni lè mọ àṣìṣe ara rẹ̀? Wẹ̀ mí mọ́ ninu àṣìṣe àìmọ̀ mi.

  • Who can understand his errors? Cleanse me from secret faults.

13. Pa èmi iranṣẹ rẹ mọ́ kúrò ninu ẹ̀ṣẹ̀ àmọ̀-ọ́n-mọ̀-dá; má jẹ́ kí wọ́n jọba lórí mi. Nígbà náà ni ara mi yóo mọ́, n kò sì ní jẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀ ńlá.

  • Keep back your servant also from presumptuous sins; let them not have dominion over me: then I shall be upright, and I shall be innocent from the great transgression.

14. Jẹ́ kí ọ̀rọ̀ ẹnu mi, ati àṣàrò ọkàn mi jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà ní ojú rẹ, OLUWA ibi ààbò mi ati olùràpadà mi.

Engage with Translingua.ng

Looking to translate biblical texts or other documents into Yoruba or any other Nigerian language? Translingua.ng offers professional translation services tailored to your needs. Click the link to order your translation service today and experience the beauty of accurate, contextual translations that resonate with your audience.

This translation ensures that each verse of Psalm 19 is not only understood but felt deeply in the context of Yoruba culture and language. With Translingua.ng, you can bring any text to life in a way that speaks directly to the heart.

How can I fully understand Psalm 19 in Yoruba? To fully understand Psalm 19 in Yoruba, consider reading a translated version that provides contextual meanings for each verse. This approach ensures you grasp the nuances and cultural relevance of the text. Additionally, consulting with professional translation services like Translingua.ng can enhance your comprehension by offering accurate and culturally resonant translations.

What resources are available for translating biblical texts into Yoruba? For translating biblical texts into Yoruba, resources such as the Yoruba Bible on platforms like Bible Gateway and YouVersion are invaluable. These platforms offer contemporary translations that are both accurate and easy to understand. For professional and tailored translation needs, consider services from Translingua.ng, which specialize in translating texts while maintaining their cultural and contextual integrity.

How can I use Psalm 19 in Yoruba for spiritual growth? Using Psalm 19 in Yoruba for spiritual growth involves meditating on its verses and reflecting on their meanings in the context of your life. Each verse highlights different aspects of God’s glory and law, providing a rich source for daily reflection. To deepen your understanding, engage with translations that explain the cultural and contextual nuances, and consider using professional translation services to ensure you fully grasp the intended message.

What are the benefits of understanding Psalm 19 in Yoruba? Understanding Psalm 19 in Yoruba offers several benefits, including a deeper connection to the text through your native language and an appreciation of its cultural context. This can enhance your spiritual experience and make the teachings more relatable and impactful. Utilizing services like Translingua.ng ensures that translations are accurate and culturally appropriate, further enriching your engagement with the text.

Where can I order professional Yoruba translation services for biblical texts? For professional Yoruba translation services for biblical texts, you can visit Translingua.ng. This platform offers expert translation services that ensure your texts are translated accurately and contextually, making the biblical passages resonate deeply within the Yoruba cultural framework. Their services are tailored to meet your specific needs, ensuring high-quality translations.

Share the Fun!

Leave a comment